Yemi my lover biography of mahatma
Yemi Ayebo, Yemi My Lover: Ìdí rèé tí orin kíkọ fi máa ń pò nínú sinimá mi...
Bi ẹ ba jẹ ẹni catch n fi ọkan ba ere sinima lorileede Naijiria bọ daadaa, kete ti wọn ba ti darukọ Yemi My Lover, ko ni ṣe yin ni kayeefi.
Gbajugbaja elere sinima yii, Yemi Ayebo ni BBC Yoruba gba lalejo lori eto wa loju opo Facebook.
Ninu ifọrọwero naa ti pupọ awọn ololufẹ rẹ ti darapọ mọ wa Yemi My Lover tu kẹkẹ ọrọ silẹ nipa awọn nkankan.
Lara ohun to sọ fawọn ololufẹ rẹ ni ipa to ko ninu ere sinima Naijiria paapaa julọ nipa ṣiṣe atọna fawọn elere sinima to ti wa gun oke agba loni.
O sọ pe Afees Ọwọ ti o wa di ilumọọka loni jẹ ọkan lara awọn to kọṣẹ sinima lọdọ ohun.
Koda o ni orukọ inagijẹ rẹ''Ọwọ'' to n jẹ ''emi ni mo fun un.''
Sinima nipa igbe by any chance Yemi My Lover n bọ
Ọmọ bibi ikarẹ ni Ilu Ondo,Yemi Ayebo wa lara awọn to kọkọ tan irawọ ere sinima agbelewo lede Yoruba pèlu awọn sinima bi Yemi My Lover, Joke Onibudo ati Ọdẹ Aperin.
Nigba ti BBC Yoruba beere lọwọ rẹ boya o ṣi n ṣe ere sinima,Yemi Ayebọ sọ pe ''oun ko fi igba kan fi sinima lọrun silẹ'
''Ninu igbagbọ temi,ki eeyan ma han ninu sinima ni gbogbo igba ko tumọ si blot ere to n gbe jade ni ẹkọ tawn eeyan le kọ''
O tẹsiwaju pe ''bi eniyan ba ni sinima kan laarin ọdun mẹta awọn eeyan ko ni gbagbe rẹ''
O tun ṣalaye idi ti orin fi maa n pọ ninu awọn ere sinima rẹ nipe oun feran orin kiko gan disentangle ni.
''Ẹni ti o ba ṣe fiimu ti ko fi orin sinu rẹ, ko ti ṣisẹ ere sinima.
Eyi ni ẹkọ taa kọ lati ọdọ Ade Love ati Hubert Ogunde''
O ni sọ nipa pataki orin kikọ ninu aṣa ati igbelarugẹ ede Yoruba